Ere Idaraya

 1. Ọlọpaa

  Gómínà ìpínlẹ̀ Ogun, Dapo Abiodun ní ìjọba òun ṣe tán láti ṣèwádìí ikú ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Remo Stars tí wọ́n ní àwọn ikọ̀ SARS ṣekúpa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Odion Ighalo

  Odion Ighalo ti di ọmọ Naijiria àkọ̀kọ̀ tí yóò gbá bọ́ọ̀lù fún ikọ̀ Manchester United lẹ́yìn tó yáa lò láti Shanghai Greenland Shenhua.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: Africa Eye: Ìrírí àwọn ọ̀dọ́bìnrin tó dágbà sójú pópó àti ìrètí wọn fún ọjọ́ ọ̀la

  Shaki jẹ́ oníjà àti kọńgílá aṣẹ́wó àmọ́ tó yípadà di àwòkọ́ṣe rere fún ọ̀pọ̀ ọdọ́bìnrin tó dàgbà sójú pópó.