Ìdìbò Gómìnà Ekiti 2018

 1. Awọn to fi apẹrẹ idalẹ si gbowo

  Kọmiṣọnna ọrọ ayika ati alumọọni inu omi, Tunji Bello ṣalaye pe onijibi lawọn eeyan to n fipa ta apẹrẹ idalẹ si.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Gomina Fayemi, Ooni Ogunwusi atawọn kabiyesi ilẹ Ekiti n jiroro.

  Lẹyin ipade to ṣe pẹlu igun gbogbo ti ọrọ kan, Ọọni Ogunwusi ni ọrọ agboole oodua n, wọn si ti yanju rẹ gẹgẹ bii ọmọ Ọodua

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: Ekifest '19: Ohun t'ọ́kùnrin ń ṣe l'Ekiti, obìnrin lè ṣe é

  Adari ileeṣẹ Aṣa ni ipinlẹ Ekiti, Wale Ojo ni awọn n ko awọ n aṣa awọn jade lati ṣe afihan wọn f'araye.