Eto ẹkọ

 1. Unilag

  Di instruction come after di Senate - wey get di power over education - do meeting on Wednesday 14 July.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Wole Soyinka gba BBC Yorùbá lálejò nínú igbó kìjikìji tó kọlé sí

  Báa ṣe ń bi í nípa Soyinka lòun náà ń tọ́ka sí Soyinka kan nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀.

 3. Video content

  Video caption: Jeleosinmi Art Centre: Ibùdó yìí ló ń tọ́ ọ̀dọ́ sọ́nà nípa iṣẹ́ ọnà àti àṣà dípò ìwà àìda

  Nigba to n ba BBC Yoruba sọrọ, Sobayo Abolore ni ọpọ ọdọ lo n fi ẹsẹ gbalẹ kiri, ti esu si n bẹ wọn nisẹ, lo mu ki oun da ibudo ti wọn yoo ti kọ nipa isẹ ọna ati asa wa silẹ.

 4. Video content

  Video caption: Alakuko/Elega Schools: Aráàlú ní olùkọ̀ọ́ àti akẹ́kọ̀ọ́ ti sá ní kíláàsì tí kò dára

  Nigba ti BBC Yoruba se abẹwo si awọn ile ẹkọ to wa ni abule Iyana Alakuko ati Elega, awọn olukọ ati araalu ni ọpọ olukọ ati akẹkọọ ni ko wa sile iwe mọ nitori ewu to wa nibẹ.