Lilo oogun

 1. Zainab Aliyu ninu aṣọ ajọ NDLEA

  Baba Zainab sọ fun BBC pe oun dupẹ lọwọ Eleduwa fun ayipada to ba aye ọmọ oun lẹyin to darapọ mọ ajọ NDLEA tan.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Yemisi Oyedepo

  Broadcast Journalist

  Captain Walz ti kọ́kọ́ bọ́ra sí hòhò l'àdúgbò kí o tó lọ lu Lẹ́ksọrà ní ọja kejì- Baba Captain Walz

  Iṣẹlẹ yi gbode kan loju opo ayelujara tawọn eeyan si n reti igbesẹ ti fasiti naa yoo gbe lori ọrọ yi

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: Ibadan shoprite killing: Ọmọ tí mo tọ́ tí mo mọ̀ f'ọ́dún 21, bí wọ́n ṣe wá bá igbó lápò rẹ

  Mọlẹbi Akintunde n wa omije loju pe ọmọ afi ki Ọlọrun ṣedajọ, awọn Ọlọ́pàá ni amugbo ni - Tani ka gbagbọ?

 4. egbòogi olóró igbo

  Gomina Rotimi Akeredolu gbe imọran yii kalẹ nibi ipade apero kan to waye lori anfaani ati iwulo ọgbin igbo ni Naijiria, eyi to waye nilu Akurẹ lọjọ Aje.

  Kà Síwájú Síi
  next