Aisan Iba

 1. Abẹrẹ wọara eeyan kan

  Ijọba ibilẹ mẹfa ni iwadii ijọba ipinlẹ Eko fihan pe arun yii ti de bayii, eyi ti eeyan lee ko lati ara igbin to wa ninu omi ti ko mọ̀.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Malaria Mosquitoes: Ẹyẹ nìkan kọ́ ló ń kọrin, ẹ̀fọn náà ń kọ

  Àwọn oníwadìí ìjìnlẹ̀ ní awọn lee kọ orin ifẹ laarin awọn ẹfọn lati lee da wahala silẹ lagbo wọn.