Isẹda Takọ-tabo

 1. Video content

  Video caption: Adeyemi Olubunmi Crown: Láti ìgbà ti mo ti fún ọkọ mi ni ẹ̀bùn mọ́tò ni ìfẹ́ wa ti yàtọ̀

  Arabinrin Gbadewole Olubunmi gba awọn obinrin niyanju lati ni iṣẹ lọwọ ki wọn le ni ominira lati ra ohun to wu wọn fun ẹni to wu wọn.

 2. Video content

  Video caption: Adene Oluwabukola Deborah: Bàbá mi kò kọ́kọ́ fọwọ́ sí iṣẹ́ ìlù lílù ṣùgbọ́n....

  Adene Deborah sọ irinajo rẹ lati ilẹẹkọ lọ sinru Naijiria ko to di alùlù ògo ati aránṣọ lẹ́yìn tó ṣetan nile ẹkọ giga.

 3. Video content

  Video caption: Ilú òyìnbò ní mo lọ lásìkò Covid ló gún mi ni kẹ̀ṣẹ́ láti bẹ̀rẹ̀

  Oluwawemimo Tade, obìnrin àgbẹ̀ tó làmìlaaka jùlọ ní ìpínlẹ̀ Ondo ni kò si àwáwí fún ẹnikẹ́ni láti má ṣe iṣẹ́ àgbẹ̀

 4. Orúkọ ọkọ̀ òfurufú tíwọ́n bi ọmọ Afganistan si ni wọ́n sọ

  Ọkọ̀ òfurufú Boeing C-17 ti àwọn ọmọogun ilẹ̀ Amẹrika ti wọ́n mán pè ni Reach nípa lílò àwọn àtopọ̀ nọ́mbà ni wọ́n sọ orúkọ ọmọtun ti wọ́n dóòlà àwọn òbí rl ni Afganistan.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Video content

  Video caption: Female Car Painter: Èmi ní obìnrin àkọ́kọ́ tí yóò máa ṣiṣẹ́ akunmọ́tò ní Ibadan

  Modupe Olagunju ba BBC Yoruba sọrọ lori bo se bẹrẹ isẹ kikun mọto ni ọda ati ọpọ idojukọ to n ba pade lẹnu isẹ naa.