Eto Irinna

 1. Ijamba ọkọ

  Oludari ileesẹ FRSC nipinlẹ Ogun, Ahmed Umar, to fi idi isẹlẹ naa mulẹ salaye pe ere asapajude ati yiya ọkọ silẹ nibi ti ko tọ, lo sokunfa ijamba naa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Flying car: Ọkọ̀ tí ń fò, ọ̀nà àbáyọ kan rèé sí ìṣòro 'go slow' lágbègbè rẹ

  Ni ilu Slovakia ni wọn ti kọkọ dan an wo.

 3. Video content

  Video caption: Ibadan Gas tanker accident: Ọdọọdún la máa ń gbé igbá àgbo lọ́jà Bode àmọ́ àwọn kan kọ̀ lọ

  Sàráà fún ọjọ́ méje ló yẹ ká ṣe àmọ́ àwọn kan kọ̀ ló fa ìjàmbá Táńkà gáàsì tó pa èèyàn - Iyaloja Bode Ibadan

 4. Aworan lati ibi ijmaba ọkọ ni Bode, Ibadan

  Gẹgẹ bi awọn to ṣoju wọn ṣe sọ ọ, ọkọ naa bẹrẹ si ni ṣina lati Idi Arere to si yi wọ inu ọja Bode.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Seyi Makinde

  Kọmiṣọna fun iṣẹ ode ati eto irinna ni ipinlẹ naa, Ọjọgbọn Dahud Kehinde Shangodoyin lo sọ bẹẹ ninu ifọrọwerọ kan pẹlu BBC Yoruba.

  Kà Síwájú Síi
  next