Aarin gbungbun Ilẹ Europe

  1. Video content

    Video caption: Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìnira lojú àwọn ọ̀dọ́ ilẹ̀ Áfíríkà t''o ń wá ìgbé ayé rere lọ sí Yúróòpù ń rí

    Irinajo okun meditarenia lọ si Yuroopu ni irinajo to buru julọ lagbaye; o ti gba ẹmi to le ni ẹgbẹrun lọna ogun(20,000)