Orilẹede Burundi

 1. Ìjọba Burundi yóò kọ̀wé lọ rọ́kún nílé fún àwọn tó dípò ìjọba mú tí wọ́n sì tún ń yàn àlè

  Gẹ́gẹ́ bí ìdarí náà ṣe wá ni pé gbogbo àwọn tó bá ti ní ìyàwó sílẹ̀ tí wan tún ni àlè síta ni wọ́n yóò le kúrò lẹ́nu iṣẹ́.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Ngendera Albert: Mi ò fẹ́ kí wọ́n máa pa ọ̀ọ̀nì ni mo ṣe ń rà wọ̀n

  Albert ti ní ọ̀ọ̀ni tó tó ogójì nínú ọgbà rẹ̀ báyìí.