Nollywood

 1. Ọjọ́ méje péré ní afún ọ kí o fi yọ sínímọ́ IKU NI lójú òpó Youtube bíbẹ̀ẹ́ kọ́.... Ẹgbẹ́ THURIST

  Ẹgbẹ THURIST wa n ké pé ẹgbẹ́ TAMPAN àti Odunlade Adekola láti gbé àwọn ìgbéṣẹ̀ yìí lẹ́yẹ o sọkà.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Peter Fatomilola ní àìsí ẹ̀kọ́ ń mú káwọn òṣèré tíátà ó máá ṣe oun tí kò tọ́.

  Baba Peter Fatomilọla, Ọkan gboogi ninu awọn elere tiata lorilẹede Naijiria ṣalaye pe igbakugba ati iwọkuwọ n pagidina lilo ere tiata fun idagbasoke awujọ.

 3. Chiwetalu Agu

  Ninu fidio naa, awọn ologun kan da bọọsi kan ti wọn kọ Chukwuetalu films si lara wọn si wọ oṣere naa bọlẹ titi ti ero fi tu jade afigba ti iro ibọn le wọn sa lọ.

  Kà Síwájú Síi
  next