Ìbàdàn

 1. Ọdunlade gbe Sanyẹri soke.

  Ilu Ibadan ti n gbalejo awọn gbajumọ osere tiata to wa se ipade apapọ ọlọdọọdun wọn, nibiti wọn yoo ti yan awọn oloye ẹgbẹ tuntun.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Aworan Minisita feto Irinajo Naijiria,Rotimi Amaechi

  Bí àwọn èèyàn kan ti ṣe ń kan sárá sí ìjọba làwọn 'míràn ní Iju tí àwọn yoó ti wọ ọkọ̀ ojú irin náà ti jìnà jù

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Seyi Makinde

  Seyi Makinde fikun pe ki Oyo gba akoso LAUTECH ko tumọ si pe mo fẹ kẹyin si awọn eeyan wa to wa nipinlẹ Ọsun nitori ẹbi kannaa ni wa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Awọn ọba mọkanlelogun nilẹ Ibadan

  Ọba Lekan Balogun ni awọn yoo pada lọ pe ẹjọ miran lori igbesẹ tijọba gbe nitori ko ro idagbasoke ilẹ Ibadan lapapọ ko to se bẹẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Video content

  Video caption: Illegal Rehab Centre: A le ni ogójì tí wan n kó 'sinú ìyará kékeré kan níle Ọlọrẹ

  BBC fọ̀rọ̀ wa àwọn ti ìpínlẹ̀ Oyo gbà kúrò lábẹ́ ìmúninígbèkùn nílé Aafa Ọlọre ní Ibadan, ojú wọn ri to!