Eto Iselu Naijiria

 1. ileegbimọ aṣofin ipinlẹ edo

  Oludari agba fun igbimọ awọn gomina ní ó pọn dandan fún Oshiomole láti kọwé fipò sílẹ̀ pẹ̀lú ìròyìn tó ń jáde láti Edo pe àwọn olóyè ẹgbẹ́ APC yọ lóyè.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Ọkọ ofurufu Bristow

  Agbẹnusọ fun ileeṣẹ ọkọ ofurufu Naijiria yi ni awọn ko ri ọna mii gbe e gba ju ki awọn da awọon oṣiṣẹ silẹ lọ lasiko Covid-19 yi.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Mamman Daura

  Awọn eniyan ti bẹrẹ si ni fesi si ọrọ ti ọrẹ timọ-timọ aarẹ Buhari sọ nipa ẹni to tọ lati jẹ aarẹ ni Naijiria.

  Kà Síwájú Síi
  next