Ọrọ aje

 1. Food prices in Nigeria

  United Capital Management sọ pe ọwọngogo ounjẹ ti Naijiria n koju lọwọ yii n ṣafihan pe o ṣeeṣe ki ounjẹ tun wọn ju bo ṣe wa yii lọ to ba maa fi di ọdun to n bọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Agolo afẹfẹ idana gaasi

  Ni bi a ṣe n sọrọ yii, owo agolo silinda oniwọn 12.5kg ti wọn n ra ni ẹgbẹrun mẹrin naira (N4000) loṣu kini ọdun 2021 gbera lọ si ẹgbẹrun meje ati ẹẹdẹgbẹrin naira (N7,800) loṣu kẹsan ọdun 2021 kan naa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Zainab Ahmed

  Minisita tun mẹnu ba bi awọn ọmọ Naijiria ṣe n paya lori owo ti ijọba n ya, o ni "o ṣi wa ni odinwo ohun ti wọn le ya torinaa ki ẹnikẹni ma ṣe bẹru".

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Muhammadu Buhari

  Gẹgẹ bi ijọba ti ṣe sọ, apapọ owo ti wọn ya ko ti ju ida mejilelogun ninu ida ọgọrun owo ti Naijiria ba pa wọle.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Aworan awọn Gomina

  Inu atẹjade onigun mẹfa kan ti wọn fi sita lọjọ Aje ni awọn Gomina wọn yi ti ni awọn ṣetan lati tako ajọ FIRS lori gbigba owo ori.

  Kà Síwájú Síi
  next
 6. Awọn isẹlẹ to n da ilu ru

  BBC Yoruba se akojọpọ awọn isẹlẹ akanilaya ti ko ba tun sọ orilẹede yii sinu ogun abẹle keji nibayii ta n sami ọdun Kọkanlelọgọta ti Naijiria gba ominira.

  Kà Síwájú Síi
  next