Lilọ-bibọ ero

 1. Video content

  Video caption: Mali sex slave returnee: Báàlù la rò pé a máa wọ̀ lọ Mali, ìrìn òṣù kan gbáko lá rìn láti

  Irọ n gori irọ ni wọn fi mu Omolara Abiyeye atawọn ọdọbinrin kan lọ ṣe owo aṣẹwo ni orilẹede Mali. "Ọ̀rẹ́-ẹ̀gbọ́n-ọ̀rẹ́ mi tí mo ń bá sọ̀rọ̀ lórí fóònù ló ní òun yóò mú mi lọ Mali

 2. Abike Dabiri-Erewa, awọn ọmọ Naijira ni Oman

  Ọkan lara awọn ọmọ Naijria lọhun kigbe pe "A n ṣiṣẹ takun takun tori mọlẹbi wa ni, ẹ ran wa lọwọ, a wa ninu wahala o!".

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: Africa Eye Migrants: Àwọn tó ń fẹsẹ̀ rìn sálọ orílẹ̀èdè míì ṣe fídíò ráńṣẹ́ sílé

  Iṣẹlẹ yii ko jẹ ko ya eeyan lẹnu pe wọn n ku lọna tabi ki ọpọlọpọ wọn pada di atọrọjẹ loju popo.

 4. Gloria Taye Bright

  Omolola Ajayi tí orí kóyo ní oko ẹru Lebanon lẹyin to fi fidio léde sórí ẹ̀rọ ayélujára, tó sì ké gbajarè fún ìrànwó kúrò ní òrílẹ̀edè náà.

  Kà Síwájú Síi
  next