Awọn isẹ taa yan laayo

 1. Video content

  Video caption: Samuel Oluwafemi sọ bí Covid 19 ṣe bí ìdíje oníjó àti eré fún àwọn Odi àti Adití sí rere

  Samuel James Oluwafemi to n kọ Odi ati Aditi ni ijo ati ere itage sọ ohun oju ri to ati ibi to ku si.

 2. Video content

  Video caption: Adepoju Abdulsalamm ẹni ọdun 18 tó n fi kẹ̀kẹ́ dára fi kiri ẹja tó fi n tà wàràwàrà

  Wo Adepoju Abdulasalam ọdọmọkunrin to n kiri ẹja fi ran iya rẹ opó lọwọ lati ri owó fi gbọ bukata ile

 3. Video content

  Video caption: Ebun Oloyede Olaiya Igwe sọ ohun tí ojú rẹ̀ rí lásìkò àìsàn kídìnrín tó yọ ọ́ lẹ́nu

  Gbajugbaja oṣere naa, Olaiya Igwe fi imoore rẹ han si Olodumare ati àwọn alaanu rẹ̀ ti ko jẹ ko ti di okú.

 4. Noosi

  Ni ipinlẹ Delta ni Abubakar ti sọ ọrọ yii lasiko to n gba awọn Nọọsi ti wọn ṣẹṣẹ ṣe idanwo abajade tan ni iyanju nipinlẹ naa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Video content

  Video caption: Abiodun Duro Ladiipo, Moremi: Ǹ kò pé '40' ti Bàbá fi papòdà ṣùgbọ́n mo kọ̀ láti 'remarry'

  Moremi

 6. Foluke iyabo Oko

  Foluke Daramola ti ke gbajare sita pe ara ogbontarigi osere ni, Iyabo Oko ko ya lati ọdun melo sẹyin ti ebi ati ara si ti na owo to pọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 7. Video content

  Video caption: Joke Silver: Olu, ó tó gẹ́ pẹ̀lú obìnrin yìí níkan tó ń ba ẹ ṣeré ìfẹ́ nínú sinimá

  Joke Silver sọ̀rọ̀ lórí ẹ̀sùn ìfipábálòpọ̀ Busola Dakolo àti Biodun Fatoyinbo COZA