Isẹ

 1. SERAP

  SERAP fi ọrọ yii lede lasiko ti wọn gbe iwadii jade lori ẹsun iwa ibajẹ ni ẹka eto ilẹra, eto ẹkọ ati omi to n sakoba fun awọn ọmọ Naijiria kalẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. CBN

  Banki apapọ lorilẹede Naijiria, CBN ti fi lede ọna ti awọn eniyan le gba lati ri owo ayalọ fun awọn eniyan ti ajakalẹ Boko Haram ṣe ipalara fun ọrọ aje.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Lizzy Anjorin

  Lizzy Anjorin ṣalaye loju opo Instagram rẹ pe lẹ́yìn ọdún mẹ́rìnlélógún tí oun bí àkọ̀bí, ni oun tó bí ọmọ tuntun míì.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Video content

  Video caption: Africa Eye: ÀṣÍrí ìhà tí ìjọba kọ sí àwọn òṣìṣẹ́fẹ̀yìntì Nàìjíríà rèé

  Wahala riri owo ifẹyinti awọn oṣiṣẹfẹyinti gba ni Naijiria kii ṣe ọrọ ọmọ oloṣu mẹta.

 5. Video content

  Video caption: Jimoh John Yakubu Ogi seller: Èmi ni mo sọ òwò kékeré tí ìyá mi ń ṣe di ńlá

  Ẹni ọdun mọkanlelogun ni Yakubu to

 6. Video content

  Video caption: World Water Day: Wo ìlú tí èèyan àti àgùntàn, màálù ti ń pín omi kanṣoṣo mu

  Ọpọlọpọ eniyan to fẹ gbe ni ilu naa ni awọn o le maa mu ẹrẹ̀ ni tawọn ni wọn ṣe feré gée.

 7. Video content

  Video caption: Plane crash in Abuja: Ìyàwó Olasunkanmi Olawunmi ọ̀kan lára àwọn Ságẹ́ńtì tó kú l'Abuja

  Omolola Olawumi ni Sunkanmi lo n gbọ gbogbo bukata ile ti ko si fi oun atawọn ọmọ rẹ ṣere.