Ele owo ọja

 1. Awọn isẹlẹ to n da ilu ru

  BBC Yoruba se akojọpọ awọn isẹlẹ akanilaya ti ko ba tun sọ orilẹede yii sinu ogun abẹle keji nibayii ta n sami ọdun Kọkanlelọgọta ti Naijiria gba ominira.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Ẹgbẹ osisẹ n sewọde

  Awọn ọmọ Naijiria ni owo oṣu oṣiṣẹ ko ka nkankan, aanu Ọlọrun ni wọn fi n gbera, ti ọpọlọpọ oṣiṣẹ si ti di onigbese.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Ẹyin Ọmọ Naijiria, ẹ ma reti lati ra epo bẹntirol ni 200 naira o kere ju - IPMAN

  Arakunrin Osatuyi ni o da oun loju wi pe gbogbo nkan ni yoo gbe owo lori nitori epo bẹntirol lo ma n sọ bi ọja yoo ṣe ri lọrilẹede Naijiria.

  Kà Síwájú Síi
  next