Ẹgbẹ to nja fẹtọ Ẹni

 1. Aworan awọn oluwọde EndSARS kan

  Ṣaaju eyi ni aileeṣẹ ọmọ ogun Naijiria ti kọkọ sẹ kanlẹ pe iroyin ofege ni iroyin to ni awọn lawọn yinbọn lu awọn oluwọde ni Lekki Tollgate.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. SERAP

  SERAP fi ọrọ yii lede lasiko ti wọn gbe iwadii jade lori ẹsun iwa ibajẹ ni ẹka eto ilẹra, eto ẹkọ ati omi to n sakoba fun awọn ọmọ Naijiria kalẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Lagos

  Ikede igbimọ tuntun naa lo waye nibi ipade awọn akọroyin kan ti kọmiṣona fun ọrọ awọn ọdọ ati idagbasoke awujọ, Olusegu Dawodu, ṣe onigbọnwọ rẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. EndSARS Panel

  Ti ẹ ko ba gbabe, ogunjọ, oṣu Kẹwaa, ọdun 2020 ni rogbodiyan bẹ silẹ lasiko ti awọn ọmọ ogun ṣina ibọn bolẹ fun awọn oluwọde EndSARS ni iloro ọhun.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Yoruba Nation: Fi pánpẹ́ ọba mú Akintoye kí ó ríran wò, àwọn ẹgbẹ ajijagbara Yoruba si ààrẹ Buhari

  Ẹgbẹ́ Ajìjàgbara Yoruba Self Determination ni ti Buhari bá fi gbe Banji Akitoye, yóò túbọ̀ da omi àlááfìa Nàìjíríà tí kò tòrò tẹ́lẹ̀ rú ni.

  Kà Síwájú Síi
  next
 6. David Oyedepo

  Oyedepo ni awọn olusọaguntan ti oun le n saisan bakan naa wọn ko so eso rere, gẹgẹ bi gbedeke ti oun fun wọn lati jere o kere ju emi mejila lọsẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 7. Aworan Igboho

  Malik Olusegun Falola sọ fun awọn akọroyin pe ijọba Benin mọọmọ fi Igboho si ahamọ ni, ki awuyewuye to n waye lori ọrọ rẹ le dinku.

  Kà Síwájú Síi
  next
 8. Sunday Igboho:Orííre lo jẹ fún Sunday igboho bí ọwọ́ òfin kò ṣe bàá ni Nàìjíríà-Femi Falana

  "DSS ko ni agbára kankan lábẹ́ lati lọ mu ènìyàn tó ṣẹ irú ẹ̀sun ẹ̀sẹ̀ ti ìjọba fi kan Sunday Igboho, òfin kílódé tí ìjọba ko bọ̀wọ̀ fún òfin"

  Kà Síwájú Síi
  next