Ẹkọ nipa yiya aworan ile ati kikọ rẹ

 1. Awọn oṣiṣẹ LASEMA nibi ile to wo ni Ikoyi

  Kọmiṣọnna eto iroyin nipinlẹ Eko, Ọgbẹni Gbenga Omotoso lo fọrọ yii lede lalẹ Ọjọru loju Facebook ijọba ipinlẹ Eko.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Ile to wo ni Ikoyi

  Kọmiṣọna eto iroyin nipinlẹ Eko fidi rẹ mulẹ pe awọn oṣiṣẹ iṣẹlẹ pajawiri si n tẹsiwaju lati ṣawari awọn eeyan labẹ ogiri alapa ile to wo naa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Awọn oṣiṣẹ NEMA nibi ile to wo ni Ikoyi

  Gomina Babajide Sanwo-Olu fidi rẹ mulẹ pe eeyan mẹẹdogun ni Eledua ko yọ nibi iṣẹlẹ naa nigba ti wọn ti ri oku eeyan mejilelogoji yọ nibẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Bulọọku ikọle

  Oludamọran pataki fun Gomina ipinlẹ Ondo lori iṣẹ ode ati ọgbọn inu, Ọgbẹni Doyin Odebowale lo kede aṣẹ ijọba ipinlẹ Ondo ọhun.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Ile n jo

  Iroyin to n tẹ wa lọwọ ni wipe ọpọlọpọ ile n jo ni ilu Akure bi eto iburawọle Gomina Akeredolu naa ṣe n lọ lọwọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 6. Emmanuella, iya ati aburo rẹ

  Ọdun 2010, to jẹ ọdun mẹwa sẹyin ni wọn bi Emmanuela, to si ti pe ọdun marun to ti bẹrẹ awada sise lawọn oju opo ayelujara.

  Kà Síwájú Síi
  next