Ofin

 1. Video content

  Video caption: Africa Eye: Ọpọ̀ obìnrin ní wọn pa, fipá bá lòpọ̀ tàbí ṣe léṣe lásìkò ìgbélé Coronavirus

  Ẹka ọtẹlẹmuyẹ BBC Africa Eye gbe abọ iwadii sita nipa ọpọ iwa ipa ti wọn se si awọn obinrin lasiko igbele Covid-19 ọlọsẹ meji ni orilẹede Kenya.

 2. Aworan idanimọ ilana ọm oodua

  Ẹgbẹ Ilana Ọmọ oodua to jẹ olori agbarijọpọ gbogbo ẹgbẹ to n ja fun idasilẹ ilẹ Yoruba ṣalaye pe awọn ko mọ nipa rẹ

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Awọn adari kansu tẹlẹ naa

  Owo naa ti ijọba ti san lo wa n da wahala silẹ bayii lagbo awọn adari iṣejọba ibilẹ tẹlẹ naa ti wọn pe orukọ wọn ni EX-ALGON.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Ọga ọlọpaa Ọnadẹkọ atawọn ọga ọlọpaa kan

  O tun ṣalaye pe awọn ọlọpaa ti kan lu igbo Onigaari fun bi ẹẹmẹta ni ifọwọsowọpọ pẹlu awọn ọlọdẹ ati vijilante lagbegbe naa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Video content

  Video caption: Ẹlẹ́wọ̀n: Ọgbà ẹ̀wọ̀n ni mo ti kàwé yege ní ìdánwò Jamb

  Ẹlẹ́wọ̀n kan ní ọgbà ẹ̀wọ̀n Ìkòyí ní ìlú Èkó ní inú ọgbà ni òun ti sorí rere nítori ibẹ̀ ni òun ti kàwé yege ìdánwò Jamb.