Idọti afẹfẹ

 1. Saudi Arabia

  Iṣẹ akanṣẹ Neom jẹ ọkan lara afojusun Mohammed, lati wa ọna miran ti orilẹ-ede Saudi Arabia fi le pa owo wọle, yatọ si owo epo rọbi.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Njẹ ọ mọ̀ pé mímí afẹ́fẹ́ tí kò dára lè fa àìsàn?

  Ajọ eleto ilera lagbaye, WHO ni ẹni to n mi eemi ti ko dara sinu dabi ẹni to n fa siga mejila lojoojumọ.

 3. ile to bajẹ lasiko ijamba ina

  Koda, ọpọ mọto ti wọn gbe kalẹ si adugbo naa lo bajẹ tan pata, eeyan mẹẹdọgbọn n gba itọju nigba ti ọpọ eeyan si di alainile lori.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Video content

  Video caption: Thomas Crowther ṣe àtúpalẹ̀ ìwádìí yìí ni orilẹ-ede àádọrin ní àgbáyé

  Ìwádìí ìí ló fihàn pé bí àwọn kòkòrò kan ṣe ń dín májèlé kù nínú afẹ́fẹ́ ti ò ń mí síni náà ni àwọn kòkòrò míì ń pọ májèlé sínú afẹ́fẹ́.