Tí a fiṣọwọ́ ní 13:19 13 Ẹrẹ̀nà 202113:19 13 Ẹrẹ̀nà 2021Ìhòhò ọmọlúàbí ní òṣèrébìnrin yìí fi lọ sí àmi ẹ̀yẹ tí wọ́n pè é síLara ẹwu to wọ de ibi ami ẹyẹ ọhun jẹ aṣọ ti wọn fi awọ rakunmi ṣe ati aṣọ kan to ni ẹjẹ lara.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 11:39 27 Èrèlè 202111:39 27 Èrèlè 2021Wo àwọn ìlú tó jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ àti èèwọ̀ ni kí ènìyàn kú níbẹ̀Ni ọkan lara awọn ilu naa, bi eeyan ba ku, mọlẹbi oku yoo sun ẹwọn.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 19:23 2 Sẹ́rẹ́ 202119:23 2 Sẹ́rẹ́ 2021Ṣé Pochettino lè gba ife ẹ̀yẹ UEFA Champions League tí PSG ń wá fún wọn?Pochettino ti buwọ luwe adehun lati ṣiṣẹ gẹgẹ akọnimọọgba fun ikọ agbabọọlu PSG fun ọdun ọlọdun meji.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 9:54 23 Ọ̀pẹ̀ 20209:54 23 Ọ̀pẹ̀ 2020Agbébọn yìnbọn pa ọlọ́pàá mẹ́ta lẹ́ẹ̀kanṣoṣo ní Saint-Justawọn ọlọpaa si n gbiyanju lati mọ boya afunrasi ọhun jona mọ ile tabi na papa bora.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 17:43 10 Bélú 202017:43 10 Bélú 2020Àwọn orílẹ̀-èdè kan tún ti kéde kó nílé-ó-gbélé nítorí coronavirusOrilẹ-ede Germany, lo kọkọ tun kede isede coronavirus nilẹ Europe, eyi to ti fa awuyewuye jakejado ilẹ naa.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 5:32 4 Bélú 20205:32 4 Bélú 2020US election 2020: Bi kò tilẹ̀ wọlé, ẹ wo ayípadà tí Ààrẹ Trump mú bá awọn orilẹede ní àgbáyéỌjọ Kẹwaa, Oṣu Kọkanla, ọdun 2020 ni idibo sipo aarẹ naa yoo waye lorilẹede Amerika.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 17:03 29 Ọ̀wàrà 202017:03 29 Ọ̀wàrà 2020Agúnbẹ kan gún èèyàn mẹ́ta pa ní ilé ìjọsìn Notre Dame basilicaIleesẹ Ọlọpaa nilẹ Faranse ko ti le sọ idi ti ikọlu ilu Nice naa fi waye.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 7:44 8 Ọ̀wàrà 20207:44 8 Ọ̀wàrà 2020Olivier Giroud fi àràmọ̀ndà góòlù méjì ṣayẹyẹ ìfẹsẹ́wọnsẹ̀ ọgọ́rùn ún tó gbá fún FranceGoolu mẹsan an ni agbaọjẹ Thierry Henry fi ju Giroud lọ eyi ti o si lanfaani lati ba a ati lati ju u lọ.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 11:04 29 Owewe 202011:04 29 Owewe 2020Ṣó yẹ kí akẹ́kọ̀ọ́ tàbùkù mi torí mo ya ‘Tatoo’ sí gbogbo ara?- Olùkọ́ yaríObi kan gẹgẹ bi Helaine ṣe sọ, lo fẹjọ sun pe, ki oun maṣe kọ awọn ọmọ mọ nitori aworan ara oun n dẹrun ba awọn akẹkọọ.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 12:25 10 Owewe 202012:25 10 Owewe 2020Ìjàmbá iná míràn tún wáyé ní pápákọ̀ ojú omi BeirutIkọ alagbelebu pupa tilu Beirut ni ko sẹni to fara pa tabi ku ninu ijamba ina naa amọ awọn eeyan kan, to sun mọ ina naa, ko le mi daadaa.Kà Síwájú Síinext