Alao Akala

  1. Video content

    Video caption: May 29: Akala, Aleshinloye sọ̀rọ̀ lórí ọdún kan Seyi Makinde gẹ́gẹ́bíi gómìnà

    Ni ọjọ kọkandinlogun oṣu karun ni yoo pe ọdun kan fun ọpọ awọn gomina ti aarẹ atawọn gomina miran yoo si tun maa ṣayajọ ọdun kan ni saa keji wọn nipo.