Orilẹede Syria

 1. Abu Bakr al-Baghdadi

  Ẹgbẹ́ ọmọ ogun Syria ní alamí tí wọ́n bẹ̀ lọ́wẹ̀ jí àwọ̀tẹ́lẹ̀ Abu Bakr al-Baghdadi tó jẹ́ olórí ẹgbẹ́ agbésùmọ̀mí Islamic State kí ọwọ́ tó tẹ̀ ẹ́.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Mohammed Emwazi, Aine Davis, Alexanda Kotey ati El Shafee Elsheikh

  Trump ń kó àwọn náà kúro ní Syria nítorí ìbẹ̀rù pé wọ́n leè bọ́ kúro nínú ẹ̀wọn lẹ́yìn ìkọlù ọmọ ogun ilẹ̀ Turkey ságbègbè náà.

  Kà Síwájú Síi
  next