Ilọrin

 1. Gomina

  Awọn ọlọpaa ni ipinlẹ Kwara ti bẹrẹ iwadii lẹyin ti wọn ba oku ọmọbinrin kan ninu ile itura ti oun ati ọkunrin kan jọ wa

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. UNILORIN

  Nigba ti BBC kan si agbẹnusọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Kwara, Ajayi Olasunkanmi lori iṣẹlẹ ọhun, o ni lootọ ni akẹkọọ naa ti jade laye.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: Saki Iron pot: Kò sí agbo ilé tẹ́ẹ dé ní Saki tẹ́ ò ní bá oníṣẹ́ kòkò àmọ àwọn ọmọ wa ń sá

  Oloye Baba Ewe Mathew Ogunrinde àti Arabinrin Emily ṣalaye bi wọn ṣe maa n lọ sí Togo láti kọ nipa ojulowo koko irin.

 4. Video content

  Video caption: Erosion in Ilorin: Kòtò tó wà níbí jìn ju ilé ìgbẹ́ lọ́! Ẹ̀mí wa ò tiẹ̀ balẹ̀ mọ́

  Wọn ṣalaye pe bi awọn ọmọ ba ti wa nileewe bayii, wahala ni.

 5. Oyedepo

  Oyedepo lo sọ ọrọ naa ninu iwaasu kan to ṣe lẹyin rogbodiyan ọrọ ijaabu to waye nile ẹkọ Baptist ati ECWA ni Ilorin.

  Kà Síwájú Síi
  next