Ọgba Ewọn

 1. Aregbesola

  Ọga agba ileeṣẹ to n ri si ọrọ ọgba ẹwọn ni Naijiria lo paṣẹ pe ki wọn bẹrẹ iwadii lori ohun to ṣokunfa ikọlu naa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Ọgba ẹwọn Owerri

  Ikọlu mii tun waye si olu ileeṣẹ ọlọpaa miran ni ipinlẹ Imo lẹyin ọjọ kan ti ikọlu akọkọ waye

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Rauf Aregbesola

  Ọgbẹni Aregbe ní gbogbo awọn to ba wa nidi ikọlu naa ni wọn yoo fi panpe ofin mu ti wọn yoo si fi wọn jofin.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Owerri prison

  A ko tii le sọ ni pato awọn to wa nidii akọlu naa, gbogbo akitiyan wa lati kan si ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ ọhun lo ja si pabo.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Video content

  Video caption: Olusegun Obasanjo: Ọmú ìyá mi ti mo fi ń mùkọ ni kekere ló jẹ ki ń lókun

  Gbogbo ohun ribiribi ti mo ti gbé ilé aye ṣe Ọlọ́run yọ̀nda rẹ̀ fun mi ni kìí ṣe mímọ̀ọ́ṣẹ àti agbára mi ló jẹ ki gbé ilé àyé ṣe rere

 6. Mọto ọgba ẹwọn Okitipupa

  Alarina ileesẹ ọgba ẹwọn l'Ondo ni awọn janduku naa wa pẹlu ibọn, ada atawọn ohun ija oloro lati kọlu ọgba ẹwọn Okitipupa

  Kà Síwájú Síi
  next