Igbagbọ ninu ilana ijọ Aguda

 1. Daddy Freeze ati Isaac Oyedepo

  Odu ni Daddy Freeze nipa titako awọn ojiṣẹ Ọlọrun, kii ṣe aimọ fun oloko, o ti tako Biṣọọbu David Oyedepo naa ri nipa awn igbesẹ rẹ kan.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Pasitọ Taiwo ati Nomthi Odukoya

  Nomthi fẹ Pasitọ Taiwo Odukoya ni oṣu Kinni, ọdun 2010, lẹyin ọdun marun un ti iyawo rẹ akọkọ, Bimbo Odukoya kú ninu ijamba baalu niluu Port Harcourt.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. TB Joshua ati Iyawo rẹ

  Ijọ SCOAN ṣalaye ninu atẹjade ọhun pe ''aya oloogbe Evelyn ṣi n ṣọfọ lọwọ lẹyin ti ọkọ rẹ wọ kaa ilẹ sun tan lọjọ kẹsan oṣu keje ọdun 2021.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Wale Oke

  Aarẹ Pentecostal Fellowship of Nigeria, PFN, alufa Wale Oke ani awọn Kristẹni kọ ṣiṣe ayẹwo iwe ofin eyi ile aṣofin n pe fun lọwọlọwọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Awọn eeyan o n jọsin ni sọọsi

  Pasitọ Femi Ajifowowe ni ko si ohun to wa ninu isin "Cross-over night" ju kí eeyan fi ọna ara rẹ le Ọlọrun lọwọ ninu gbadura lọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 6. Fr Ejike Mbaka

  Awọn ọmọ ijọ Mbaka n dunkooko lati pa awọn akọroyin BBC danu nitori pe wọn ni wọn n kọ 'awọn iroyin ti ko dara nipa Fada Mbaka'.

  Kà Síwájú Síi
  next