Okoowo

 1. Bags of rice

  Aburo Opeyemi, Alima, to wa ninu ṣọọbu ọhun lasiko naa ta irẹsi fun okunrin naa pẹlu igbagbọ pe aburo rẹ ni awọn ọdọkunrin meji ọhun.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Adekemi Corps member potter: Kò sóhun tó leè yà mí ya iṣẹ́ mi, mo nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ dé góńgó

  Agunbanirọ ni Adekemi lọwọlọwọ ṣugbọn o kọ lati dara le wiwa iṣẹ ijọba kaakiri.

 3. Bulọọku ikọle

  Oludamọran pataki fun Gomina ipinlẹ Ondo lori iṣẹ ode ati ọgbọn inu, Ọgbẹni Doyin Odebowale lo kede aṣẹ ijọba ipinlẹ Ondo ọhun.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Lagos

  Ikede igbimọ tuntun naa lo waye nibi ipade awọn akọroyin kan ti kọmiṣona fun ọrọ awọn ọdọ ati idagbasoke awujọ, Olusegu Dawodu, ṣe onigbọnwọ rẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. David Oyedepo

  Oyedepo ni awọn olusọaguntan ti oun le n saisan bakan naa wọn ko so eso rere, gẹgẹ bi gbedeke ti oun fun wọn lati jere o kere ju emi mejila lọsẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 6. Video content

  Video caption: Adewale and Funmilayo Deaf couple taylor: Ọmọ ọdun 6 ni Ọ̀kadà gbá mi, ọmọ ọdún 9 ni ìyàwó

  Adewale ṣalaye bí oun ati iyawo rẹ ti wọn jọ jẹ odi ṣe yii mọọ titi ti wọn ko fi ri idẹyẹsi lori iṣẹ ọwọ wọn mọ.