Ẹlẹyamẹya

 1. Aworan Instagram

  Awọn alaṣẹ ileeṣẹ Instagram n tọka si iṣẹlẹ idẹyẹsi to waye lẹyin ifẹsẹwọnsẹ aṣekagba idije Euro 2020 laarin ik agbabọọlu England ati Italy gẹgẹ bii ara ohun to sun wọn si igbesẹ tuntun yii.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. George Floyd

  Ọkan lara agbẹjọro fawọn ọlọpaa ni, ẹrọ ayaworan to wa lara awọn ọlọpaa naa fihan pe, ọkan lara wọn lo ni ki Floyd gbẹnu dakẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: Belly Mujinga: Bí iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ní UK ṣe parí ẹ̀ṣùn rẹ̀ mú kí àwọn adúláwọ̀ fa ìbínú yọ

  BBC Yoruba ba ọkọ oloogbe Belly Mujinga sọrọ, to si ni ohun fẹ ki gbogbo agbaye maa ranti iyawo oun bii obinrin takuntakun

 4. Video content

  Video caption: Black lives Matter: Ọmọ Naijiria sọ ìrírí rẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ọlọ́pàá nílẹ̀ Amerika.

  Ọmọ Naijiria to n gbe nilẹ Amerika,Yomi Faparusi ti sọ iru igbeaye ti awọn alawọdudu ma n gbe ni oke okun nitori idẹyẹ si ni.

 5. Dilibe Onyeama, adulawọ akọkọ to pari iwe rẹ nile ẹkọ Eton,

  Dilibe Onyeama kọ iwe kan nipa iwa ẹlẹyamẹya ti oju rẹ ri nileewe naa ati bi ti ile ẹkọ naa ko se gba a laaye lati pada wa sibẹ mọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 6. Ipara ti wọn fi n bora

  Obìnrin ẹni ọdún mọ́kànlélégún kan ti gba ẹ̀mí ara rẹ̀ ní India, látàri bí ọkọ rẹ̀ ṣe ń fi ṣẹlẹ́yà nítorí ó jẹ́ àwọ̀ rẹ̀ dúdú.

  Kà Síwájú Síi
  next