Idibo Amẹrika 2020

 1. Adewale Adeyemo

  Adewale Adeyemo wa lara awọn ti awọn eniyan rreti pe aarẹ ti wọn dibo yan, Joe Biden yoo kede rẹ lati ba a ṣiṣẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: US Vice President:Ẹ wo ìtàn obìnrin àkọ́kọ́ tí yóò jẹ igbákejì Ààrẹ ilẹ́ Amẹrika?

  Ṣẹnetọ Kamala Harris ni obinrin alawọdudu akọkọ ti yoo jẹ igbakeji aarẹ lorilẹede Amerika.

 3. Video content

  Video caption: America Inauguration Joe: Wo àwọn eré orí ìtàgé tí Donald Trump ṣe kó tó fi ipò aàrẹ sílẹ̀

  Lọ́là ni Donald Trump jáde ti Joe Biden yoo bẹ̀rẹ̀ si ni tukọ aleefa ijọba orilẹ-ede America

 4. Video content

  Video caption: Joe Biden Innauguration: Tani ìyàwó Joe Biden tí yóò jẹ obìnrin akọ̀kọ nílẹ̀ Amẹrika?

  Ogunjọ, oṣu yii ni wọn yoo burawọle fun Joe Biden gẹgẹ bi aarẹ aadọta ilẹ Amẹrika.