Oju opo ikansira Instagram

 1. Mark Zuckerberg

  Zuckerberg sọ pe orukọ tuntun naa tumọ si pe ẹnikẹni to ba fẹ maa lo eyikeyi ninu awọn ohun ti ileeṣẹ naa n ṣe yoo ni lati kọkọ lo oju opo Facebook.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Aworan Instagram

  Awọn alaṣẹ ileeṣẹ Instagram n tọka si iṣẹlẹ idẹyẹsi to waye lẹyin ifẹsẹwọnsẹ aṣekagba idije Euro 2020 laarin ik agbabọọlu England ati Italy gẹgẹ bii ara ohun to sun wọn si igbesẹ tuntun yii.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Lizzy Anjorin

  Awọn agbẹjọro Toyin ni nkan ti Lizzy kọ nipa onibara awọn lo wa lati baa lorukọ jẹ, ti ko ba si tete tọrọ aforijin, ọrọ ọhun yoo beere fun atilẹyin ofin nile ẹjọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Lizzy Anjorin

  Awọn ololufẹ Toyin Abraham ati Lizzy Anjorin ti n gbena woju ara wọn loju opo Instagram nitori pe Lizzy ko gbe Toyin larugẹ lasiko to bimọ.

  Kà Síwájú Síi
  next