Iwa ọti amupara

  1. Video content

    Video caption: Gabola Church: Ẹnu gbẹ ní Ṣọ́ọ̀ṣì wa tírí òfin ìséde Covid-19

    Ṣọ́ọ̀ṣì tí wọ́n ti ń fi ọtí àmupara bá Ọlọ́run sọ̀rọ̀ ní kí ìjọba dẹwọ́ọ òfin títà ọtí lásìkò Covid-19.