Orilẹede China

 1. Video content

  Video caption: Ṣhómólú l‘Eko: Ibùdó ìwé títẹ̀ àkọ́kọ́ ní W.Afrika

  Àdúgbò Sómólú ní ìlú Èkó gbajú-gbaja fún ìwé títẹ̀ láà sí ìdààmú kankan, kò sì sí ilé kan ní Sómólú, tí kìí se ìwé ni wọ́n ń tẹ̀ níbẹ̀.

 2. Video content

  Video caption: Awọn n so igi mo ẹgbẹ oke gogooro ti Huashan ni Ariwa-Iwọ oorun orilẹede China.

  Awọn eniyan mọ oke gogooro ti Huashan ni Ariwa-Iwọ oorun orilẹede China yii fun bi o ti n yọ ati bi o se ri gudugudu.

 3. Babajide Sanwo-Olu

  Ìjọba ìpínlẹ̀ Eko ti kéde pé òun yóò bẹ̀rẹ̀ pínpín oúnjẹ fún àwọn èèyàn lásìkò ìgbélé Coronavirus.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Video content

  Video caption: Coronavirus: Kò sí ẹni tí coronavirus kò le mú

  Alaye lori ayederu iroyin to sọ pe coronavirus ko le mu alawọ dudu