Aṣa

 1. Video content

  Video caption: Adejoke Ewaede: Ìfẹ́ àṣà Yorùbá ló mú kí ń pinnu láti máa wọ aṣọ àdìrẹ̀ nìkan

  Adejoke Somoye wa gbe imọran kalẹ fun awọn ọba alaye nilẹ Yoruba pe ki wọn fi ofin de sisọ ede miran ninu aafin wọn lẹyin ede Yoruba lọna ati gbe ede wa larugẹ.

 2. Toko taya

  Labẹ ofin orilẹ-ede Japan, ọmọbabinrin yoo sọ ipo rẹ nu to ba fẹ araalu ti ko wa lati idile ọba, amọ, ofin yii ko de ọmọbakunrin ilẹ Japan rara.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: Peter Fatomilola ní àìsí ẹ̀kọ́ ń mú káwọn òṣèré tíátà ó máá ṣe oun tí kò tọ́.

  Baba Peter Fatomilọla, Ọkan gboogi ninu awọn elere tiata lorilẹede Naijiria ṣalaye pe igbakugba ati iwọkuwọ n pagidina lilo ere tiata fun idagbasoke awujọ.

 4. Video content

  Video caption: Akomolede ati Asa: Ọ̀rọ̀ Asopò ni á ń gbéyẹ̀wò pẹ̀lú Arabìnrin Tope Atoyebi láti Ilorin

  Arabinrin Tope Atoyebi lati emmanuel Baptist College Tanke, Ilorin ni olukọ wa lonii lori eto Akomolede ati Asa lori BBC Yoruba.

 5. Video content

  Video caption: Ṣé ìwọ mọ̀ pé Olodumare lè lo Aje láti gbé ẹ lọ síbi ire?- Abiodun Fatomilola

  Oloye Abiodun Fatomilola sọrọ nipa ajọṣẹpọ tó wà láàrin Aje, Babalawo ati eeyan ati bi Olodumare ṣe n lo wọn fun ara wọn.

 6. Video content

  Video caption: Yinka Oke: Àwọn tó ń hun aṣọ òkè ayé àtijọ́ náà ló hun tiwa

  Àrà aṣọ òkè kò dúró lórí ọ̀ṣọ̀ ìlẹ̀kẹ̀ níkan mọ́, oríṣríṣi ni ohun tí àwọn ènìyàn fí ń buyì kú aṣọ òkè.