Egbẹ Oselu Onigbalẹ (APC)

 1. Akeredolu

  Oludije mẹwaa lo ba gomina Akeredolu du aṣia oludije ipo gomina ipinlẹ Ondo lẹgbẹ oṣelu APC, ṣùgbọ́n mẹta yọwọ́.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Gomina Babajide Sanwo-Olu atawọn eleto ilera to n tọju covid-19

  Ẹru n ba ọpọ eeyan nipinlẹ Eko pe o ṣeeṣe ki iyanṣẹlodi awọn dokita ko pẹ eyi ti yoo ṣakoba fun itọju awọn alaarun covid-19.

  Kà Síwájú Síi
  next