Ipinlẹ Zamfara

 1. Awakọ baalu to ja laarin awọn ọga ologun

  Oludari ẹka alarina ati eto iroyin fun ileesẹ ologun ofurufu, Edward Gabkwetto ni lọjọ Aiku, ọjọ Kejidinlogun osu Keje ọdun 2021 ni deede aago kan ku isẹju mẹẹdogun, ni isẹlẹ naa waye.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Zamfara: Ìdí tí a fi mú àwọn olùfẹ̀hónúhàn lórí pé wọ́n tẹ òfin ètò ààbò lójú.

  Sáájú ní àwọn ará ìlú tí sọ fún BBC pé, ìwọ́de ìfẹ̀hónúhàn náà kò ṣẹ̀yìn bi àwọn ọlọ́pàá ṣe kọtí ikún sí awọn ẹ̀sùn tí ará ìlú ń mú lọ fún wọ́n lórí ọ̀rọ̀ aàbò.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Soldiers

  Atẹjade naa fi kun pe awọn ti ọwọ tẹ yii n ṣapẹrẹ ọrọ ti goimina ipinlẹ naa sọ ṣaaju pe, ẹnu yoo ya awọn arralu lẹyin ti aṣiri awọn to wa nidii iṣẹrubalu ba tu tan.

  Kà Síwájú Síi
  next