Ipinlẹ Plateau

 1. Video content

  Video caption: Unijos students victims: Àwọn Fulani yabo 'hostel' wa, ọpẹ́lọpẹ́ àwọn Sọ́jà tí gómìnà ìpí

  Awọn ọmọ ipinlẹ̀ Oyo ba BBC soro lori ohun toju wọn ri ni Jos ki Makinde to ran mọto wa ko wọn.

 2. Plateau Killing

  Saaju ni Gomina Simon Lalong ti kọkọ pe fun konileogbele ni ijọba ibilẹ mẹta lọjọ Satide nitori wahala to waye ni opopona Rukuba ni ijọba ibilẹ Jos North.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Coronavirus

  Mínísítà fún ètò ìlera rọ awọn ọmọ Naijira lati mu imọtoto ni pataki, lati maa fọ ọwọ wọn, ki wọn si jinna rere si alarun Coronavirus.

  Kà Síwájú Síi
  next