Màidúgùri

 1. Boko Haram

  Ninu atẹjada kan ti alukoro ileeṣẹ naa, Onyema Nwachukwu fi lede, o ni awọn afurasi naa ti iye wọn to 1,009 ti la awọn idanilẹkọọ kan kọja.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Prince Malik Ado Ibrahim: Wo bí Adama Indimi àti Prince Malik Ado ọmọ Ọba Ohinoyi ilẹ Ebira ṣe fa ayélujára ya

  Iroyin igbeyawo laarin Adama Indimi ati Arẹmọ ti n lọ kaakiri lori ayelujara ati lori iroyin awọn ileeṣẹ iroyin Naijiria eyi to waye lọjọ Abamẹta to lọ yii.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Aarẹ Buhari

  Ọrọ ibanikẹdun ni aarẹ fi ranṣẹ si ẹbi awọn to ba iṣẹlẹ naa rin ṣugbọn ọpọ awọn ọmọ Naijiria ko ba a gba a lẹrọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Fani-Kayode sọ pe ọrọ aje Naijiria ti dẹnu kọlẹ labẹ iṣejọba ààrẹ Buhari

  Femi Fani-Kayode nọ̀ka àbùkù sí aàrẹ Muhammadu Buhari lẹ́yìn tó bu ẹnu àtẹ̀ lu bí ẹgbẹ̀ Islamic State ṣe bẹ́ àwọn Krìstíẹ̀nì lórí.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Ọmọ ogun ilẹ Naijiria

  Ọmọ ológun orílẹ̀-èdè Nàìjíríà mẹ́wàá ti jẹ́ Ọlọ́run nípè lẹ́yìn ìkọlù ikọ̀ Boko Haram ní Domba, ní ìpínlẹ̀ Bornu.

  Kà Síwájú Síi
  next