Ọbabinrin Elizabeth keji

 1. Prince Philip: Ètò isinmi àrà ọ̀tọ̀ ni wọ́n ṣe ni Canterbury Cathedral lónìí

  Bó tilẹ̀ jẹ́ pé Prince Philip ti lọ síbẹ̀, ọbabinrin kò le gbàgbé rẹ̀ yóò túbọ̀ dàbí pé wọ́n jọ jòkó sẹ́gbẹ́ ará wọn.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Canberra, Australia

  Ọmọọba Philip, tó jẹ́ ọkọ Ọbabinrin Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ̀sí, Elizabeth Kejì fún ọdún mẹ́tàléláàdọ́rin kú ní Ọjọ́ Eti, ọjọ́ kẹsàn, Oṣù Kẹrin ọdún 2021.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: Prince Phillip: Duke ti Edinburgh padòdà lẹ́ni ọdún 99

  Prince Philip tó jẹ́ ọkọ ọbabinrin fún ọdún mẹtalelaadọrin ti lo akoko diẹ ni ile iwosan.