INEC

 1. Akeredolu

  Oludije mẹwaa lo ba gomina Akeredolu du aṣia oludije ipo gomina ipinlẹ Ondo lẹgbẹ oṣelu APC, ṣùgbọ́n mẹta yọwọ́.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Iná sọ lọ́fíìsì àjọ INEC l'Abuja

  Ileeṣẹ Ajọ INEC to jona l' Abuja

  Ina sọ lolu ileeṣẹ ajọ eleto abo INEC lowurọ ọjọ Ẹti.

  Iroyin sọ pe ọkan lara awọn ọfiisi ileeṣẹ naa to n mojuto ọrọ ẹgbẹ oṣelu ati idibo lo gbina.

  Atẹjade kan eyi ti alukoro ajọ INEC, Festus Okoyeṣalaye pe awọn oṣiṣẹ panapana to wa ni olu ileeṣẹ ajọ naa atawọn akẹgbẹ wọn lati olu ilu ilẹẹwa, Abuja tete ko si iṣẹ ti wọn si bomi pa ina naa ko to ṣ’ọṣẹ pupọ.

  Ajọ INEC ni ina to jo naa ko lee dawọ iṣẹ akoso ajọ naa duro rara.

  Ileeṣẹ Ajọ INEC to jona l' Abuja
  Ileeṣẹ Ajọ INEC to jona l' Abuja
  Ileeṣẹ Ajọ INEC to jona l' Abuja