Iwa-ipa nidi ibalopọ

 1. Ọmọ ati iya rẹ to n ba lopọ

  Alukoro ajọ NSCDC sọ fun BBC pe lọjọ Satide ni awọn ri aridaju pe lootọ arabinrin naa, Fati Sime ti bi ọmọ mẹta fun ọmọ rẹ gangan.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Odunlade Adekola and Adenike Hamzah

  Adenike lo fi ọrọ naa lede ninu fidio kan loju opo Instagram rẹ nibi to ti ke si awọn eeyan lati ma ba ọjọ ọla oun jẹ ninu iṣẹ tiata.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Akku Yadav

  Lara awọn iwa aburu tí àwọn ọkunrin maa n wu si awọn obinrin ninu ile ni, bii lilu ni ilu bara tabi ifipabanilopọ, to jẹ eyii to buru julọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Afurasi to ku ati eyi ti ọwọ tẹ

  DSP Oyeyemi ṣàlàyé pe awọn ọlọpaa mori le inú igbo Imala lẹyin ti ile iṣẹ ọlọpaa to wa lagbegbe naa ni awọn ri ajinigbe mẹfa pẹlu ibọn lọwọ wọn ninu igbo.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Video content

  Video caption: Joke Silver: Olu, ó tó gẹ́ pẹ̀lú obìnrin yìí níkan tó ń ba ẹ ṣeré ìfẹ́ nínú sinimá

  Joke Silver sọ̀rọ̀ lórí ẹ̀sùn ìfipábálòpọ̀ Busola Dakolo àti Biodun Fatoyinbo COZA