Irin ajo

 1. Video content

  Video caption: Travelouge: Ṣé ẹ ti gbọ́ nípa Ua Agbeto rí níbí tí ìtọ̀ kìí rùn bó bá ṣe pọ̀ tó?

  Akọja ewe ni abala Eto Ẹ kalọ si ilu mi lori eto BBC Yoruba.

 2. Video content

  Video caption: Covid-19 Pandemic funeral: A dáná sun odidi òkú èèyàn gẹgẹ bí àwọn mọlẹbí ṣe sanwó ẹ̀

  Àwọn ǹkan táa rí rí tẹlẹ tó máa ń ṣẹlẹ níbi ìsìnkú ni Bolanle Okusanya, Elétò abániṣayẹyẹ ìsìnkú sọ síta yìí.

 3. Video content

  Video caption: Lebanon Slavery: Ẹ̀yìn àti àyà máa ń dùn mí lóru tí mi ò ní lè sùn

  Ọmọ ilu Ekiti to ba wọn wa iṣẹ aje lọ Lebanon sọ bi ija ṣe waye laarin oun ati ọga rẹ.