opo ikansiraẹni twitta

 1. Lai

  Ijọba jẹ ko di mimọ pe gbogbo ọrọ to fa sababi gbigbe òté lee lori lawọn ti n wa ojutu si ni lọọlọ yii to si ni ipadabọ Twitter yoo to de.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Jack Dorsey an Buhari

  Ninu atẹjade kan ti awọn eeyan naa buwọlu, ti wọn si fi ṣọwọ si awọn akọroyin, wọn ni igbesẹ ti ijọba apapọ gbe ko ba ofin mu.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Adeboye

  Agbẹjọro Agba ni Naijiria,Abubakar Malami paṣẹ pe ki wọn fi oju gbogbo awọn to ṣi n lo ayelujara ibaraẹnidọrẹ Twitter wina ofin.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Isa Pantami

  Ṣaaju ni ileeṣẹ iroyin ori ayelujara kan ti kọkọ jabọ pe ijọba ilẹ Amẹrika ti fi orukọ Pantami sara awọn eeyan ti wọn n ṣọ loju-lẹsẹ nitori pe o n ṣe atilẹyin fun awọn agbẹsunmọmi.

  Kà Síwájú Síi
  next