Aisan Jẹjẹrẹ

 1. Video content

  Video caption: Abisayo Fakiyesi breast cancer survivor: Mo dédé rí ẹ̀jẹ̀ ní orí ọmú mi, mo ti ní bó tilẹ̀

  Abisayo ṣalaye fun BBC Yoruba ninu ifọrọwerọ kan bi o ṣe jẹ iyalẹnu pe o ri i bori lẹni to ti gbagbọ pe iku ni yoo gbẹyin oun gẹgẹ bo ṣe gbẹyin iya rẹ.

 2. Pasitọ Taiwo ati Nomthi Odukoya

  Nomthi fẹ Pasitọ Taiwo Odukoya ni oṣu Kinni, ọdun 2010, lẹyin ọdun marun un ti iyawo rẹ akọkọ, Bimbo Odukoya kú ninu ijamba baalu niluu Port Harcourt.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Dr Jingmei Li n sisẹ nile ayẹwo

  Onimọ ni ayẹwo ọyan lee sawari arun jẹjẹrẹ ọyan taa ba ri ami miran pe arun yi ti wọnu agọ ara, ti koro ọyan naa ko si to ibu eso Bluberry.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Video content

  Video caption: World Cancer Day: Mo pàdánù ọkọ àti ọ̀rẹ́ bí mo ṣe ni 'Cancer'- Iwalade Adebimpe Adetunji

  Iwalade Adetunji ni pe Ọmọ ọdun mẹsan an ni mo bẹrẹ nkan oṣu, láti igba naa ni ọyan ti ma n kan mi.

 5. Video content

  Video caption: Cancer: Àṣe ara mi ni iso ti n run gbogbo bí mo ṣe n ṣèrànwọ́ lórí jẹjẹrẹ

  Ǹjẹ́ ẹ mọ̀ ọgbọ́n àmúlò tí Ọ̀jọ̀gbọ́n lítírésọ̀, Wole Soyinka fi bọ́ yányán lọ́wọ́ àrùn jẹjẹrẹ?

 6. Video content

  Video caption: Hospital Wedding: Oṣù kan péré ni Tash fi ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Simon kó tó kú

  Simon Young tii se ọkọ Tash salaye fun BBC pe ọjọ igbeyawo oun naa ni ọjọ ti inu oun dun julọ.