Awọn arugbo

 1. Video content

  Video caption: Emma Akana Eye: Ṣé lọòtọ ni àwọn dókítà ojú máa ń yọ ojú fi rúbọ?

  Bi awọn eeyan to ba wu ṣe maa n fun ni ni awọn ẹya ara bii kindinrin, ẹjẹ ati bẹẹ bẹẹ lọ, fifunni ni oju yii kii ṣe gbogbo eeyan lo tẹwọ gba lati maa ṣe e.

 2. Video content

  Video caption: Covid-19 Pandemic funeral: A dáná sun odidi òkú èèyàn gẹgẹ bí àwọn mọlẹbí ṣe sanwó ẹ̀

  Àwọn ǹkan táa rí rí tẹlẹ tó máa ń ṣẹlẹ níbi ìsìnkú ni Bolanle Okusanya, Elétò abániṣayẹyẹ ìsìnkú sọ síta yìí.

 3. Video content

  Video caption: Africa Eye: ÀṣÍrí ìhà tí ìjọba kọ sí àwọn òṣìṣẹ́fẹ̀yìntì Nàìjíríà rèé

  Wahala riri owo ifẹyinti awọn oṣiṣẹfẹyinti gba ni Naijiria kii ṣe ọrọ ọmọ oloṣu mẹta.

 4. Video content

  Video caption: 60 years married couple: Ó dá mi lójú pé kò sí ẹni tí ọkọ mi ń ro ẹjọ́ mi fún

  Ọ̀gbẹ́ni àti Iyaafin Benjamin Awoyemi ni ọpọlọpọ iriri ti ọpọ lọkọlaya ode oni ko lee fara balẹ ṣe rara.

 5. Video content

  Video caption: 50 Year old Ajayi Folashade: Mo ti kọ́kọ́ dán an wò ní 80s àmọ́, ó kàn ṣáà ń wù mi náà ni
 6. Video content

  Video caption: Joke Silver: Olu, ó tó gẹ́ pẹ̀lú obìnrin yìí níkan tó ń ba ẹ ṣeré ìfẹ́ nínú sinimá

  Joke Silver sọ̀rọ̀ lórí ẹ̀sùn ìfipábálòpọ̀ Busola Dakolo àti Biodun Fatoyinbo COZA