Akọsilẹ Imọ

 1. Video content

  Video caption: Wole Soyinka gba BBC Yorùbá lálejò nínú igbó kìjikìji tó kọlé sí

  Báa ṣe ń bi í nípa Soyinka lòun náà ń tọ́ka sí Soyinka kan nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀.

 2. Video content

  Video caption: Lagos King: Mátikú ọba tó lo lo ọdun mẹta lórí oyé latari rogbodiyan Eko

  Omowe Bisoye Eleṣin, olukọni ni fasiti Eko ṣàlàyé ohun tó ṣokunfa kíkọ ìtàn Ọba Mátikú tó jẹ lọdun 1928 si 1931 sére oníṣe.

 3. Oladejo Okediji àti ìgbé ayé ìtàn kíkọ rẹ̀

  Àrá, ọ̀rẹ́, àwọn òǹkọ̀wé àti Mọ̀lẹ́bí olóògbé Oladejọ Okediji ń ṣe ìdáro bàbá tó yẹ kó ṣe ọjọ́ ìbí Àádọ́rùn ún ọdún láyé.

  Kà Síwájú Síi
  next