Gómìnà Kasivita fidi rẹ̀ múlẹ̀ pé "ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ti gba ẹmi àwọn ará ilú wa" bẹ́ẹ̀ lo fi ọ̀rs ìyànjú ránṣẹ́ si àwọn ẹbi ti àjálù náà dé bá àti awọn to farapa.
Kà Síwájú SíiOrilẹede Olominira Congo
Video content
Video caption: Ebola Virus: ìdí tí Ebola fi ń tàn kálẹ̀ Ebola tún ti dé DR Congo àti Uganda ní èyí tí wọ́n ní kò ṣẹ̀yìn ẹran ìgbẹ́ Àdán, Ọ̀bọ, ìnàkí àti Ìgalà.