BBC Yoruba se akojọpọ awọn isẹlẹ akanilaya ti ko ba tun sọ orilẹede yii sinu ogun abẹle keji nibayii ta n sami ọdun Kọkanlelaadọta ti ogun Biafra pari.
Elerinmo tilu Erinmo ni o yẹ kawọn ikọ Amotekun ati Civil Defence wa lagbegbe naa ni gbogbo igba lati dena ijinigbe, amọ lasiko yii, ko si nkankan nibẹ.