Ipinlẹ Lagos

 1. Bags of rice

  Aburo Opeyemi, Alima, to wa ninu ṣọọbu ọhun lasiko naa ta irẹsi fun okunrin naa pẹlu igbagbọ pe aburo rẹ ni awọn ọdọkunrin meji ọhun.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Bobrisky

  Ohun to mu ọrọ yii wa ni bi Bobrisky ṣe tabuku Tonto Dikeh loju opo Instagram rẹ pe o wọ gbese ẹgbẹlẹgbẹ miliọnu naira.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Kazeem Abonde

  Ninu atẹjade ti alukoro ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko, Adekunle Ajisebutu fi ṣọwọ si awọn akọroyin, o ni ẹmi ọga ọlọpaa ọhun sọnu lasiko ti wọn lọ fofin de awọn ọlọkada lagbegbe ọhun.

  Kà Síwájú Síi
  next