Idibo gbogboogbo 2019 lorilẹede Naijiria

 1. Bola Tinubu

  Oriṣiiriṣii nkan bii aṣọ ilewọ, fila, ounjẹ inu apo lawọn eeyan kan n pin eyi ti akọle "Tinubu fun ipo aarẹ ọdun 2023" wa lara rẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Ayo Adebanjo ati Bola Tinubu

  Adarí ẹgbẹ́ Afẹ́nifẹ́re ni Nàìjíríà, olóyè Ayo Adebanjo ní bí ó jẹ́ ọmọ òun ló fẹ́ dupò ààrẹ, òun kò ni gbárúkù tí, tí kò bá sí àtúntò Nàìjíríà.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Igbakeji gomina, Aderemi Olaniyan ati gomina Seyi makinde

  Alhaji Nureni Akanbi, tii se ọkan lara awọn agbaagba ẹgbẹ PDP to n fi apap janu nipinlẹ Oyo, ba BBC Yoruba sọrọ lori ohun tó fa ìja laarin wọn ati gomina Oyo.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Video content

  Video caption: FFK: Buhari ló ń fún àwọn Fulani láàyè láti máa pa ènìyàn'

  Fẹmi Fani Kayọde sọ̀rọ̀ lórí igbésẹ̀ to yẹ ki Aarẹ Buhari gbé láti dẹ́kun ìpànìyàn Nàìjíríà lásìkò yí